Hósíà 2:21, 22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 ‘Ní ọjọ́ yẹn, màá dáhùn,’ ni Jèhófà wí,‘Màá dá àwọn ọ̀run lóhùn,Wọ́n á sì dá ilẹ̀ lóhùn;+22 Ilẹ̀ á sì dá ọkà àti wáìnì tuntun àti òróró lóhùn;Àwọn náà á sì dá Jésírẹ́lì*+ lóhùn.
21 ‘Ní ọjọ́ yẹn, màá dáhùn,’ ni Jèhófà wí,‘Màá dá àwọn ọ̀run lóhùn,Wọ́n á sì dá ilẹ̀ lóhùn;+22 Ilẹ̀ á sì dá ọkà àti wáìnì tuntun àti òróró lóhùn;Àwọn náà á sì dá Jésírẹ́lì*+ lóhùn.