2 Àwọn Ọba 19:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Torí bí inú rẹ ṣe ń ru sí mi+ àti bí o ṣe ń ké ramúramù ti dé etí mi.+ Torí náà, màá fi ìwọ̀ mi kọ́ imú rẹ,+ màá fi ìjánu mi sáàárín ètè rẹ,Ọ̀nà tí o gbà wá ni màá sì mú ọ gbà pa dà.”+ Sáàmù 32:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ẹ má dà bí ẹṣin tàbí kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́* tí kò ní òye,+Tó jẹ́ pé ìjánu tàbí okùn la fi ń kì í wọ̀ tó bá ń ta pọ́n-ún pọ́n-únKó tó lè sún mọ́ni.”
28 Torí bí inú rẹ ṣe ń ru sí mi+ àti bí o ṣe ń ké ramúramù ti dé etí mi.+ Torí náà, màá fi ìwọ̀ mi kọ́ imú rẹ,+ màá fi ìjánu mi sáàárín ètè rẹ,Ọ̀nà tí o gbà wá ni màá sì mú ọ gbà pa dà.”+
9 Ẹ má dà bí ẹṣin tàbí kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́* tí kò ní òye,+Tó jẹ́ pé ìjánu tàbí okùn la fi ń kì í wọ̀ tó bá ń ta pọ́n-ún pọ́n-únKó tó lè sún mọ́ni.”