-
Jóṣúà 10:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Bí wọ́n ṣe ń sá fún Ísírẹ́lì, tí wọ́n sì wà níbi gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́ Bẹti-hórónì, Jèhófà rọ̀jò òkúta yìnyín ńláńlá lé wọn lórí láti ọ̀run, ó ń rọ̀ lé wọn lórí títí dé Ásékà, wọ́n sì ṣègbé. Kódà, àwọn tí yìnyín náà pa pọ̀ ju àwọn tí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì fi idà pa lọ.
-