Àìsáyà 30:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Wọ́n lọ sí Íjíbítì+ láì fọ̀rọ̀ lọ̀ mí,*+Láti wá ààbò lọ sọ́dọ̀ Fáráò,*Kí wọ́n sì fi òjìji Íjíbítì ṣe ibi ìsádi wọn!
2 Wọ́n lọ sí Íjíbítì+ láì fọ̀rọ̀ lọ̀ mí,*+Láti wá ààbò lọ sọ́dọ̀ Fáráò,*Kí wọ́n sì fi òjìji Íjíbítì ṣe ibi ìsádi wọn!