Àìsáyà 66:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Torí pé iná ni Jèhófà máa fi ṣèdájọ́,Àní, ó máa fi idà rẹ̀ bá gbogbo ẹran ara* jà;Àwọn tí Jèhófà pa sì máa pọ̀ rẹpẹtẹ.
16 Torí pé iná ni Jèhófà máa fi ṣèdájọ́,Àní, ó máa fi idà rẹ̀ bá gbogbo ẹran ara* jà;Àwọn tí Jèhófà pa sì máa pọ̀ rẹpẹtẹ.