Àìsáyà 30:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Wò ó! Orúkọ Jèhófà ń bọ̀ láti ọ̀nà jíjìn,Inú ń bí i gan-an, ó sì ń bọ̀ pẹ̀lú àwọsánmà* tó ṣú bolẹ̀. Ìbínú kún ètè rẹ̀,Ahọ́n rẹ̀ sì dà bí iná tó ń jẹni run.+ Náhúmù 1:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Jèhófà jẹ́ Ọlọ́run tó fẹ́ kí a máa jọ́sìn òun nìkan ṣoṣo,+ ó sì ń gbẹ̀san;Jèhófà ń gbẹ̀san, ó sì ṣe tán láti bínú.+ Jèhófà ń gbẹ̀san lára àwọn elénìní rẹ̀,Ó sì ń to ìbínú rẹ̀ jọ de àwọn ọ̀tá rẹ̀.
27 Wò ó! Orúkọ Jèhófà ń bọ̀ láti ọ̀nà jíjìn,Inú ń bí i gan-an, ó sì ń bọ̀ pẹ̀lú àwọsánmà* tó ṣú bolẹ̀. Ìbínú kún ètè rẹ̀,Ahọ́n rẹ̀ sì dà bí iná tó ń jẹni run.+
2 Jèhófà jẹ́ Ọlọ́run tó fẹ́ kí a máa jọ́sìn òun nìkan ṣoṣo,+ ó sì ń gbẹ̀san;Jèhófà ń gbẹ̀san, ó sì ṣe tán láti bínú.+ Jèhófà ń gbẹ̀san lára àwọn elénìní rẹ̀,Ó sì ń to ìbínú rẹ̀ jọ de àwọn ọ̀tá rẹ̀.