Ìsíkíẹ́lì 39:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ìwọ yóò ṣubú sí orí àwọn òkè Ísírẹ́lì,+ ìwọ àti gbogbo ọmọ ogun rẹ àti àwọn èèyàn tí yóò wà pẹ̀lú rẹ. Màá mú kí onírúurú ẹyẹ aṣọdẹ àti ẹran inú igbó fi ọ́ ṣe oúnjẹ.”’+
4 Ìwọ yóò ṣubú sí orí àwọn òkè Ísírẹ́lì,+ ìwọ àti gbogbo ọmọ ogun rẹ àti àwọn èèyàn tí yóò wà pẹ̀lú rẹ. Màá mú kí onírúurú ẹyẹ aṣọdẹ àti ẹran inú igbó fi ọ́ ṣe oúnjẹ.”’+