-
Málákì 1:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 “Bó tilẹ̀ jẹ́ pé Édómù sọ pé, ‘Wọ́n ti fọ́ wa túútúú, àmọ́ a máa pa dà, a ó sì tún àwọn àwókù náà kọ́,’ ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ nìyí, ‘Wọ́n máa kọ́ ọ; àmọ́ màá ya á lulẹ̀, wọ́n sì máa pè wọ́n ní “ilẹ̀ ìwà burúkú” àti “àwọn èèyàn tí Jèhófà ti ta nù títí láé.”+
-