Àìsáyà 7:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Jèhófà wá sọ fún Àìsáyà pé: “Jọ̀ọ́, jáde lọ pàdé Áhásì, ìwọ àti Ṣeari-jáṣúbù* ọmọ rẹ,+ ní ìpẹ̀kun ibi tí adágún omi tó wà lápá òkè ń gbà,+ níbi ọ̀nà tó lọ sí pápá alágbàfọ̀.
3 Jèhófà wá sọ fún Àìsáyà pé: “Jọ̀ọ́, jáde lọ pàdé Áhásì, ìwọ àti Ṣeari-jáṣúbù* ọmọ rẹ,+ ní ìpẹ̀kun ibi tí adágún omi tó wà lápá òkè ń gbà,+ níbi ọ̀nà tó lọ sí pápá alágbàfọ̀.