Àìsáyà 22:20, 21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 “‘Ní ọjọ́ yẹn, màá pe ìránṣẹ́ mi, Élíákímù+ ọmọ Hilikáyà, 21 màá wọ aṣọ rẹ fún un, màá de ọ̀já rẹ mọ́ ọn pinpin,+ màá sì gbé àṣẹ* rẹ lé e lọ́wọ́. Ó máa di bàbá àwọn tó ń gbé Jerúsálẹ́mù àti ilé Júdà.
20 “‘Ní ọjọ́ yẹn, màá pe ìránṣẹ́ mi, Élíákímù+ ọmọ Hilikáyà, 21 màá wọ aṣọ rẹ fún un, màá de ọ̀já rẹ mọ́ ọn pinpin,+ màá sì gbé àṣẹ* rẹ lé e lọ́wọ́. Ó máa di bàbá àwọn tó ń gbé Jerúsálẹ́mù àti ilé Júdà.