Jeremáyà 49:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Sí Damásíkù:+ “Ìtìjú ti bá Hámátì+ àti Áápádì,Nítorí wọ́n ti gbọ́ ìròyìn búburú. Ìbẹ̀rù mú kí ọkàn wọn domi. Wọ́n dà bí òkun tó ń ru gùdù, tí kò ṣeé mú rọlẹ̀.
23 Sí Damásíkù:+ “Ìtìjú ti bá Hámátì+ àti Áápádì,Nítorí wọ́n ti gbọ́ ìròyìn búburú. Ìbẹ̀rù mú kí ọkàn wọn domi. Wọ́n dà bí òkun tó ń ru gùdù, tí kò ṣeé mú rọlẹ̀.