Òwe 21:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Ọkàn ọba dà bí odò ní ọwọ́ Jèhófà.+ Ibi tí Ó bá fẹ́ ló ń darí rẹ̀ sí.+