2 Kíróníkà 6:40 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 40 “Ní báyìí, ìwọ Ọlọ́run mi, jọ̀wọ́, ṣí ojú rẹ, kí o sì tẹ́tí sí àdúrà tí a bá gbà ní* ibí yìí.+ Sáàmù 65:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ìwọ Olùgbọ́ àdúrà, ọ̀dọ̀ rẹ ni onírúurú èèyàn* yóò wá.+