Àìsáyà 37:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Bóyá Jèhófà Ọlọ́run rẹ máa gbọ́ ọ̀rọ̀ Rábúṣákè tí olúwa rẹ̀ ọba Ásíríà rán láti pẹ̀gàn Ọlọ́run alààyè,+ tí á sì pè é wá jíhìn nítorí àwọn ọ̀rọ̀ tí Jèhófà Ọlọ́run rẹ ti gbọ́. Torí náà, gbàdúrà+ nítorí àṣẹ́kù tó yè bọ́ yìí.’”+
4 Bóyá Jèhófà Ọlọ́run rẹ máa gbọ́ ọ̀rọ̀ Rábúṣákè tí olúwa rẹ̀ ọba Ásíríà rán láti pẹ̀gàn Ọlọ́run alààyè,+ tí á sì pè é wá jíhìn nítorí àwọn ọ̀rọ̀ tí Jèhófà Ọlọ́run rẹ ti gbọ́. Torí náà, gbàdúrà+ nítorí àṣẹ́kù tó yè bọ́ yìí.’”+