2 Kíróníkà 32:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ó tún kọ àwọn lẹ́tà+ láti fi pẹ̀gàn Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì+ àti láti fi sọ̀rọ̀ òdì sí i, ó ní: “Bí àwọn ọlọ́run àwọn orílẹ̀-èdè kò ṣe gba àwọn èèyàn wọn lọ́wọ́ mi,+ bẹ́ẹ̀ ni Ọlọ́run Hẹsikáyà kò ní gba àwọn èèyàn rẹ̀ lọ́wọ́ mi.”
17 Ó tún kọ àwọn lẹ́tà+ láti fi pẹ̀gàn Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì+ àti láti fi sọ̀rọ̀ òdì sí i, ó ní: “Bí àwọn ọlọ́run àwọn orílẹ̀-èdè kò ṣe gba àwọn èèyàn wọn lọ́wọ́ mi,+ bẹ́ẹ̀ ni Ọlọ́run Hẹsikáyà kò ní gba àwọn èèyàn rẹ̀ lọ́wọ́ mi.”