Àìsáyà 1:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Tí kì í bá ṣe pé Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun dá díẹ̀ nínú wa sí,À bá ti dà bíi Sódómù gẹ́lẹ́,À bá sì ti jọ Gòmórà.+ Àìsáyà 10:20, 21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Ní ọjọ́ yẹn, àwọn tó ṣẹ́ kù ní Ísírẹ́lìÀti àwọn tó yè bọ́ ní ilé Jékọ́bùKò tún ní gbára lé ẹni tó lù wọ́n;+Àmọ́ wọ́n máa fi òtítọ́ gbára lé Jèhófà,Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì. 21 Àṣẹ́kù nìkan ló máa pa dà,Àṣẹ́kù Jékọ́bù, sọ́dọ̀ Ọlọ́run Alágbára.+
9 Tí kì í bá ṣe pé Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun dá díẹ̀ nínú wa sí,À bá ti dà bíi Sódómù gẹ́lẹ́,À bá sì ti jọ Gòmórà.+
20 Ní ọjọ́ yẹn, àwọn tó ṣẹ́ kù ní Ísírẹ́lìÀti àwọn tó yè bọ́ ní ilé Jékọ́bùKò tún ní gbára lé ẹni tó lù wọ́n;+Àmọ́ wọ́n máa fi òtítọ́ gbára lé Jèhófà,Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì. 21 Àṣẹ́kù nìkan ló máa pa dà,Àṣẹ́kù Jékọ́bù, sọ́dọ̀ Ọlọ́run Alágbára.+