Àìsáyà 31:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Bí àwọn ẹyẹ tó ń já ṣòòrò wálẹ̀, ni Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ṣe máa gbèjà Jerúsálẹ́mù.+ Ó máa gbèjà rẹ̀, ó sì máa gbà á là. Ó máa dá a sí, ó sì máa gbà á sílẹ̀.”
5 Bí àwọn ẹyẹ tó ń já ṣòòrò wálẹ̀, ni Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ṣe máa gbèjà Jerúsálẹ́mù.+ Ó máa gbèjà rẹ̀, ó sì máa gbà á là. Ó máa dá a sí, ó sì máa gbà á sílẹ̀.”