-
Jóṣúà 10:12, 13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Lọ́jọ́ tí Jèhófà ṣẹ́gun àwọn Ámórì níṣojú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, ìgbà yẹn ni Jóṣúà sọ fún Jèhófà níṣojú Ísírẹ́lì pé:
13 Bí oòrùn ṣe dúró sójú kan nìyẹn, òṣùpá ò sì kúrò títí orílẹ̀-èdè náà fi gbẹ̀san lára àwọn ọ̀tá rẹ̀. Ṣebí wọ́n kọ ọ́ sínú ìwé Jáṣárì?+ Oòrùn dúró sójú kan ní àárín ojú ọ̀run, kò sì tètè wọ̀ fún nǹkan bí odindi ọjọ́ kan.
-