-
2 Àwọn Ọba 20:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Hẹsikáyà ti béèrè lọ́wọ́ Àìsáyà pé: “Àmì+ wo ló máa jẹ́ kó dá mi lójú pé Jèhófà máa mú mi lára dá àti pé màá lè lọ sí ilé Jèhófà ní ọjọ́ kẹta?”
-