Àìsáyà 3:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Dípò òróró básámù,+ òórùn ohun tó jẹrà ló máa wà;Dípò àmùrè, okùn;Dípò irun tó rẹwà, orí pípá;+Dípò aṣọ olówó ńlá, aṣọ ọ̀fọ̀;*+Àpá tí wọ́n fi sàmì dípò ẹwà.
24 Dípò òróró básámù,+ òórùn ohun tó jẹrà ló máa wà;Dípò àmùrè, okùn;Dípò irun tó rẹwà, orí pípá;+Dípò aṣọ olówó ńlá, aṣọ ọ̀fọ̀;*+Àpá tí wọ́n fi sàmì dípò ẹwà.