Jóẹ́lì 3:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ẹ ó sì mọ̀ pé èmi ni Jèhófà Ọlọ́run yín, tó ń gbé ní Síónì, òkè mímọ́ mi.+ Jerúsálẹ́mù yóò di ibi mímọ́,+Àwọn àjèjì* kò sì ní gbà á kọjá mọ́.+
17 Ẹ ó sì mọ̀ pé èmi ni Jèhófà Ọlọ́run yín, tó ń gbé ní Síónì, òkè mímọ́ mi.+ Jerúsálẹ́mù yóò di ibi mímọ́,+Àwọn àjèjì* kò sì ní gbà á kọjá mọ́.+