Jeremáyà 31:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun, Ọlọ́run Ísírẹ́lì sọ nìyí: “Wọ́n á tún ọ̀rọ̀ yìí sọ ní ilẹ̀ Júdà àti ní àwọn ìlú rẹ̀, nígbà tí mo bá kó àwọn èèyàn rẹ̀ tó wà lóko ẹrú pa dà: ‘Kí Jèhófà bù kún ọ, ìwọ ibùgbé òdodo,+ ìwọ òkè mímọ́.’+
23 Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun, Ọlọ́run Ísírẹ́lì sọ nìyí: “Wọ́n á tún ọ̀rọ̀ yìí sọ ní ilẹ̀ Júdà àti ní àwọn ìlú rẹ̀, nígbà tí mo bá kó àwọn èèyàn rẹ̀ tó wà lóko ẹrú pa dà: ‘Kí Jèhófà bù kún ọ, ìwọ ibùgbé òdodo,+ ìwọ òkè mímọ́.’+