Àìsáyà 54:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Jèhófà máa kọ́ gbogbo àwọn ọmọ* rẹ,+Àlàáfíà àwọn ọmọ* rẹ sì máa pọ̀ gan-an.+