Ìsíkíẹ́lì 17:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 “‘“Bí mo ti wà láàyè,” ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí, “Bábílónì ni yóò kú sí, níbi tí ọba* tó fi í* jọba ń gbé, ẹni tí òun kò ka ìbúra rẹ̀ sí, tó sì da májẹ̀mú rẹ̀.+
16 “‘“Bí mo ti wà láàyè,” ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí, “Bábílónì ni yóò kú sí, níbi tí ọba* tó fi í* jọba ń gbé, ẹni tí òun kò ka ìbúra rẹ̀ sí, tó sì da májẹ̀mú rẹ̀.+