Ẹ́kísódù 21:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 “Tí o bá ra Hébérù kan ní ẹrú,+ kí ó sìn ọ́ fún ọdún mẹ́fà, àmọ́ ní ọdún keje, kí o dá a sílẹ̀ láìgba ohunkóhun.+
2 “Tí o bá ra Hébérù kan ní ẹrú,+ kí ó sìn ọ́ fún ọdún mẹ́fà, àmọ́ ní ọdún keje, kí o dá a sílẹ̀ láìgba ohunkóhun.+