Jeremáyà 15:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Bí wọ́n bá sì bi ọ́ pé, ‘Kí ló máa ṣẹlẹ̀ sí wa?’ kí o sọ fún wọn pé, ‘Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Àjàkálẹ̀ àrùn máa pa àwọn kan lára yín! Idà máa pa àwọn kan lára yín!+ Ìyàn máa pa àwọn míì lára yín! Àwọn kan lára yín sì máa lọ sóko ẹrú!”’+ Jeremáyà 15:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Màá sì sọ wọ́n di ohun àríbẹ̀rù lójú gbogbo ìjọba ayé+ nítorí ohun tí Mánásè ọmọ Hẹsikáyà, ọba Júdà ṣe ní Jerúsálẹ́mù.+ Jeremáyà 29:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 “‘Màá fi idà,+ ìyàn àti àjàkálẹ̀ àrùn lé wọn, màá sọ wọ́n di ohun àríbẹ̀rù lójú gbogbo ìjọba ayé,+ màá sì sọ wọ́n di ẹni ègún àti ohun ìyàlẹ́nu, ohun àrísúfèé+ àti ẹni ẹ̀gàn láàárín gbogbo orílẹ̀-èdè tí màá fọ́n wọn ká sí,+
2 Bí wọ́n bá sì bi ọ́ pé, ‘Kí ló máa ṣẹlẹ̀ sí wa?’ kí o sọ fún wọn pé, ‘Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Àjàkálẹ̀ àrùn máa pa àwọn kan lára yín! Idà máa pa àwọn kan lára yín!+ Ìyàn máa pa àwọn míì lára yín! Àwọn kan lára yín sì máa lọ sóko ẹrú!”’+
4 Màá sì sọ wọ́n di ohun àríbẹ̀rù lójú gbogbo ìjọba ayé+ nítorí ohun tí Mánásè ọmọ Hẹsikáyà, ọba Júdà ṣe ní Jerúsálẹ́mù.+
18 “‘Màá fi idà,+ ìyàn àti àjàkálẹ̀ àrùn lé wọn, màá sọ wọ́n di ohun àríbẹ̀rù lójú gbogbo ìjọba ayé,+ màá sì sọ wọ́n di ẹni ègún àti ohun ìyàlẹ́nu, ohun àrísúfèé+ àti ẹni ẹ̀gàn láàárín gbogbo orílẹ̀-èdè tí màá fọ́n wọn ká sí,+