-
Jẹ́nẹ́sísì 15:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Ó wá kó gbogbo rẹ̀, ó gé wọn sí méjì-méjì, ó sì kọjú wọn síra,* àmọ́ kò gé àwọn ẹyẹ náà.
-
-
Jẹ́nẹ́sísì 15:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 Nígbà tí oòrùn wọ̀, tí ilẹ̀ sì ti ṣú, iná ìléru tó ń rú èéfín fara hàn, iná ògùṣọ̀ sì kọjá láàárín àwọn ẹran tó gé.
-