-
Diutarónómì 28:26Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
26 Òkú rẹ á di oúnjẹ fún gbogbo ẹyẹ ojú ọ̀run àtàwọn ẹranko orí ilẹ̀, láìsí ẹnikẹ́ni tó máa lé wọn dà nù.+
-
-
Sáàmù 79:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Wọ́n ti fi òkú àwọn ìránṣẹ́ rẹ ṣe oúnjẹ fún àwọn ẹyẹ ojú ọ̀run,
Wọ́n sì ti fi ẹran ara àwọn ẹni ìdúróṣinṣin rẹ fún àwọn ẹran inú igbó.+
-