-
Jeremáyà 35:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Nítorí náà, à ń ṣègbọràn sí ohùn Jèhónádábù ọmọ Rékábù baba ńlá wa nínú ohun gbogbo tó pa láṣẹ fún wa, a kò sì jẹ́ fẹnu kan wáìnì, àwa fúnra wa, àwọn ìyàwó wa, àwọn ọmọkùnrin wa àti àwọn ọmọbìnrin wa.
-