Àìsáyà 65:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Torí ẹ̀ṣẹ̀ wọn àti ẹ̀ṣẹ̀ àwọn baba ńlá wọn pẹ̀lú,”+ ni Jèhófà wí. “Torí pé wọ́n ti mú ẹbọ rú èéfín lórí àwọn òkè,Wọ́n sì ti gàn mí lórí àwọn òkè,+Màá kọ́kọ́ díwọ̀n èrè wọn ní ẹ̀kúnrẹ́rẹ́.”*
7 Torí ẹ̀ṣẹ̀ wọn àti ẹ̀ṣẹ̀ àwọn baba ńlá wọn pẹ̀lú,”+ ni Jèhófà wí. “Torí pé wọ́n ti mú ẹbọ rú èéfín lórí àwọn òkè,Wọ́n sì ti gàn mí lórí àwọn òkè,+Màá kọ́kọ́ díwọ̀n èrè wọn ní ẹ̀kúnrẹ́rẹ́.”*