ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Kíróníkà 20:2, 3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 Àwọn kan wá sọ fún Jèhóṣáfátì pé: “Ọ̀pọ̀ èèyàn ti wá láti agbègbè òkun,* láti Édómù,+ kí wọ́n lè bá ọ jà, wọ́n sì wà ní Hasasoni-támárì, ìyẹn Ẹ́ń-gédì.”+ 3 Ni ẹ̀rù bá bẹ̀rẹ̀ sí í ba Jèhóṣáfátì, ó sì pinnu láti wá* Jèhófà. + Nítorí náà, ó kéde ààwẹ̀ fún gbogbo Júdà.

  • Ẹ́sítà 4:15, 16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Nígbà náà, Ẹ́sítà fún Módékáì lésì pé: 16 “Lọ, kó gbogbo àwọn Júù tó wà ní Ṣúṣánì* jọ, kí ẹ sì gbààwẹ̀+ nítorí mi. Ẹ má jẹ, ẹ má sì mu fún ọjọ́ mẹ́ta,+ ní òru àti ní ọ̀sán. Èmi àti àwọn ìránṣẹ́bìnrin mi á sì gbààwẹ̀ bákan náà. Màá wọlé lọ sọ́dọ̀ ọba, bó tilẹ̀ jẹ́ pé kò bá òfin mu, tí mo bá sì máa kú, kí n kú.”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́