Jeremáyà 36:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Bó tilẹ̀ jẹ́ pé Élínátánì+ àti Deláyà+ pẹ̀lú Gemaráyà+ bẹ ọba pé kó má sun àkájọ ìwé náà, kò gbọ́ tiwọn.
25 Bó tilẹ̀ jẹ́ pé Élínátánì+ àti Deláyà+ pẹ̀lú Gemaráyà+ bẹ ọba pé kó má sun àkájọ ìwé náà, kò gbọ́ tiwọn.