Jeremáyà 1:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ó sì dájú pé wọ́n á bá ọ jà,Ṣùgbọ́n wọn kò ní borí* rẹ,Nítorí ‘mo wà pẹ̀lú rẹ + láti gbà ọ́’ ni Jèhófà wí.”
19 Ó sì dájú pé wọ́n á bá ọ jà,Ṣùgbọ́n wọn kò ní borí* rẹ,Nítorí ‘mo wà pẹ̀lú rẹ + láti gbà ọ́’ ni Jèhófà wí.”