Jeremáyà 34:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Màá sì fi Sedekáyà ọba Júdà àti àwọn ìjòyè rẹ̀ lé ọwọ́ àwọn ọ̀tá wọn àti àwọn tó fẹ́ gba ẹ̀mí wọn* àti lé ọwọ́ àwọn ọmọ ogun ọba Bábílónì+ tó ṣígun kúrò lọ́dọ̀ yín.’+
21 Màá sì fi Sedekáyà ọba Júdà àti àwọn ìjòyè rẹ̀ lé ọwọ́ àwọn ọ̀tá wọn àti àwọn tó fẹ́ gba ẹ̀mí wọn* àti lé ọwọ́ àwọn ọmọ ogun ọba Bábílónì+ tó ṣígun kúrò lọ́dọ̀ yín.’+