32 Kí ni kí n tún sọ? Torí àkókò ò ní tó tí n bá ní kí n máa sọ̀rọ̀ nípa Gídíónì,+ Bárákì,+ Sámúsìn,+ Jẹ́fútà,+ Dáfídì,+ títí kan Sámúẹ́lì+ àti àwọn wòlíì yòókù.
36 Àní, àdánwò tí àwọn míì kojú ni pé wọ́n fi wọ́n ṣẹlẹ́yà, wọ́n sì nà wọ́n lẹ́gba, kódà ó jùyẹn lọ, wọ́n fi ṣẹkẹ́ṣẹkẹ̀ dè wọ́n,+ wọ́n sì fi wọ́n sẹ́wọ̀n.+