-
Jeremáyà 38:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 “Olúwa mi ọba, ìwà ìkà gbáà ni àwọn ọkùnrin yìí hù sí wòlíì Jeremáyà! Wọ́n ti jù ú sínú kòtò omi, ibẹ̀ ló sì máa kú sí nítorí ìyàn, torí kò sí búrẹ́dì mọ́ ní ìlú yìí.”+
-