Jeremáyà 37:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ọba Sedekáyà rán Jéhúkálì + ọmọ Ṣelemáyà àti Sefanáyà+ ọmọ àlùfáà Maaseáyà sí wòlíì Jeremáyà pé: “Jọ̀wọ́, bá wa gbàdúrà sí Jèhófà Ọlọ́run wa.”
3 Ọba Sedekáyà rán Jéhúkálì + ọmọ Ṣelemáyà àti Sefanáyà+ ọmọ àlùfáà Maaseáyà sí wòlíì Jeremáyà pé: “Jọ̀wọ́, bá wa gbàdúrà sí Jèhófà Ọlọ́run wa.”