Jeremáyà 26:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Àwọn àlùfáà àti àwọn wòlíì sì sọ fún àwọn ìjòyè àti gbogbo àwọn èèyàn náà pé: “Ikú tọ́ sí ọkùnrin yìí,+ nítorí ó sọ tẹ́lẹ̀ nípa ìlú yìí, gẹ́gẹ́ bí ẹ ti fi etí ara yín gbọ́ ọ.”+
11 Àwọn àlùfáà àti àwọn wòlíì sì sọ fún àwọn ìjòyè àti gbogbo àwọn èèyàn náà pé: “Ikú tọ́ sí ọkùnrin yìí,+ nítorí ó sọ tẹ́lẹ̀ nípa ìlú yìí, gẹ́gẹ́ bí ẹ ti fi etí ara yín gbọ́ ọ.”+