ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 3:11, 12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Àmọ́ Mósè sọ fún Ọlọ́run tòótọ́ pé: “Ta ni mo jẹ́, tí màá fi lọ bá Fáráò, tí màá sì mú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì kúrò ní Íjíbítì?” 12 Ó fèsì pé: “Èmi yóò wà pẹ̀lú rẹ,+ ohun tí yóò sì jẹ́ àmì fún ọ pé èmi ni mo rán ọ nìyí: Lẹ́yìn tí o bá ti mú àwọn èèyàn náà kúrò ní Íjíbítì, ẹ máa jọ́sìn* Ọlọ́run tòótọ́ lórí òkè yìí.”+

  • Jeremáyà 15:20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 “Màá sọ ọ́ di odi bàbà tó lágbára sí àwọn èèyàn yìí.+

      Ó dájú pé wọ́n á bá ọ jà,

      Àmọ́ wọn ò ní borí* rẹ,+

      Torí mo wà pẹ̀lú rẹ, láti gbà ọ́ àti láti dá ọ sílẹ̀,” ni Jèhófà wí.

  • Ìṣe 18:9, 10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Síwájú sí i, Olúwa sọ fún Pọ́ọ̀lù ní òru nínú ìran pé: “Má bẹ̀rù, máa sọ̀rọ̀ nìṣó, má sì dákẹ́, 10 torí mo wà pẹ̀lú rẹ,+ ẹnikẹ́ni ò ní kọ lù ọ́ láti ṣe ọ́ léṣe; nítorí mo ní ọ̀pọ̀ èèyàn ní ìlú yìí.”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́