2 Àwọn Ọba 22:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Lẹ́yìn náà, Hilikáyà àlùfáà àgbà sọ fún Ṣáfánì akọ̀wé+ pé: “Mo ti rí ìwé Òfin+ ní ilé Jèhófà.” Torí náà, Hilikáyà fún Ṣáfánì ní ìwé náà, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í kà á.+
8 Lẹ́yìn náà, Hilikáyà àlùfáà àgbà sọ fún Ṣáfánì akọ̀wé+ pé: “Mo ti rí ìwé Òfin+ ní ilé Jèhófà.” Torí náà, Hilikáyà fún Ṣáfánì ní ìwé náà, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í kà á.+