Ìdárò 4:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Jèhófà ti fi ìrunú rẹ̀ hàn;Ó ti da ìbínú rẹ̀ tó ń jó bí iná jáde.+ Ó sì ti dá iná kan ní Síónì tó jó ìpìlẹ̀ rẹ̀ run.+
11 Jèhófà ti fi ìrunú rẹ̀ hàn;Ó ti da ìbínú rẹ̀ tó ń jó bí iná jáde.+ Ó sì ti dá iná kan ní Síónì tó jó ìpìlẹ̀ rẹ̀ run.+