Jeremáyà 38:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ebedi-mélékì+ ará Etiópíà, tó jẹ́ ìwẹ̀fà* ní ilé* ọba gbọ́ pé wọ́n ti ju Jeremáyà sínú kòtò omi. Lásìkò yìí, ọba wà níbi tó jókòó sí ní Ẹnubodè Bẹ́ńjámínì,+
7 Ebedi-mélékì+ ará Etiópíà, tó jẹ́ ìwẹ̀fà* ní ilé* ọba gbọ́ pé wọ́n ti ju Jeremáyà sínú kòtò omi. Lásìkò yìí, ọba wà níbi tó jókòó sí ní Ẹnubodè Bẹ́ńjámínì,+