Jeremáyà 50:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Gbogbo àwọn tó rí wọn ti pa wọ́n jẹ,+ àwọn ọ̀tá wọn sì ti sọ pé, ‘A ò jẹ̀bi, nítorí wọ́n ti ṣẹ Jèhófà, wọ́n ti ṣẹ ibùgbé òdodo àti ìrètí àwọn baba ńlá wọn, Jèhófà.’”
7 Gbogbo àwọn tó rí wọn ti pa wọ́n jẹ,+ àwọn ọ̀tá wọn sì ti sọ pé, ‘A ò jẹ̀bi, nítorí wọ́n ti ṣẹ Jèhófà, wọ́n ti ṣẹ ibùgbé òdodo àti ìrètí àwọn baba ńlá wọn, Jèhófà.’”