-
2 Àwọn Ọba 25:24Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
24 Gẹdaláyà búra fún wọn àti fún àwọn ọkùnrin wọn, ó sì sọ pé: “Ẹ má bẹ̀rù láti sin àwọn ará Kálídíà. Ẹ máa gbé ilẹ̀ yìí, kí ẹ máa sin ọba Bábílónì, nǹkan á sì máa lọ dáadáa fún yín.”+
-
-
Jeremáyà 27:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 “‘“‘Àmọ́, orílẹ̀-èdè tó bá fi ọrùn rẹ̀ sábẹ́ àjàgà ọba Bábílónì, tí ó sì sìn ín, ni màá jẹ́ kó dúró* sórí ilẹ̀ rẹ̀,’ ni Jèhófà wí, ‘láti máa ro ó, kí ó sì máa gbé orí rẹ̀.’”’”
-