-
2 Àwọn Ọba 25:23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
23 Nígbà tí gbogbo olórí àwọn ọmọ ogun àti àwọn ọkùnrin wọn gbọ́ pé ọba Bábílónì ti yan Gẹdaláyà, lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, wọ́n wá sọ́dọ̀ Gẹdaláyà ní Mísípà. Àwọn ni Íṣímáẹ́lì ọmọ Netanáyà, Jóhánánì ọmọ Káréà, Seráyà ọmọ Táńhúmétì ará Nétófà àti Jaasanáyà ọmọ ará Máákátì pẹ̀lú àwọn ọkùnrin wọn.+
-