Jóṣúà 18:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Nígbà náà, gbogbo àpéjọ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé jọ sí Ṣílò,+ wọ́n sì to àgọ́ ìpàdé síbẹ̀,+ torí wọ́n ti ṣẹ́gun ilẹ̀ náà.+
18 Nígbà náà, gbogbo àpéjọ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé jọ sí Ṣílò,+ wọ́n sì to àgọ́ ìpàdé síbẹ̀,+ torí wọ́n ti ṣẹ́gun ilẹ̀ náà.+