-
Jeremáyà 40:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Torí náà gbogbo àwọn Júù bẹ̀rẹ̀ sí í pa dà wá láti gbogbo ibi tí wọ́n fọ́n wọn ká sí, wọ́n sì wá sí ilẹ̀ Júdà, sọ́dọ̀ Gẹdaláyà ní Mísípà. Wọ́n sì kó wáìnì àti èso ìgbà ẹ̀ẹ̀rùn jọ lọ́pọ̀lọpọ̀.
-