ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jeremáyà 40:11, 12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Gbogbo àwọn Júù tó wà ní Móábù, ní Ámónì àti ní Édómù títí kan àwọn tó wà ní gbogbo àwọn ilẹ̀ yòókù náà gbọ́ pé ọba Bábílónì ti fi àwọn kan sílẹ̀ kí wọ́n máa gbé ní Júdà àti pé ó ti yan Gẹdaláyà ọmọ Áhíkámù ọmọ Ṣáfánì ṣe olórí wọn. 12 Torí náà gbogbo àwọn Júù bẹ̀rẹ̀ sí í pa dà wá láti gbogbo ibi tí wọ́n fọ́n wọn ká sí, wọ́n sì wá sí ilẹ̀ Júdà, sọ́dọ̀ Gẹdaláyà ní Mísípà. Wọ́n sì kó wáìnì àti èso ìgbà ẹ̀ẹ̀rùn jọ lọ́pọ̀lọpọ̀.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́