Dáníẹ́lì 2:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Ó ń yí ìgbà àti àsìkò pa dà,+Ó ń mú ọba kúrò, ó sì ń fi ọba jẹ,+Ó ń fún àwọn ọlọ́gbọ́n ní ọgbọ́n, ó sì ń fún àwọn tó ní òye ní ìmọ̀.+ Dáníẹ́lì 5:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ní tìrẹ, ọba, Ọlọ́run Gíga Jù Lọ gbé ìjọba fún Nebukadinésárì bàbá rẹ, ó sọ ọ́ di ẹni ńlá, ó sì fún un ní ògo àti ọlá ńlá.+
21 Ó ń yí ìgbà àti àsìkò pa dà,+Ó ń mú ọba kúrò, ó sì ń fi ọba jẹ,+Ó ń fún àwọn ọlọ́gbọ́n ní ọgbọ́n, ó sì ń fún àwọn tó ní òye ní ìmọ̀.+
18 Ní tìrẹ, ọba, Ọlọ́run Gíga Jù Lọ gbé ìjọba fún Nebukadinésárì bàbá rẹ, ó sọ ọ́ di ẹni ńlá, ó sì fún un ní ògo àti ọlá ńlá.+