-
Ìsíkíẹ́lì 29:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Èmi yóò mú àwọn ẹrú Íjíbítì pa dà wá sí ilẹ̀ Pátírọ́sì,+ ilẹ̀ tí wọ́n ti wá, wọ́n á sì di ìjọba tí kò já mọ́ nǹkan kan níbẹ̀.
-